DAPỌ ABIỌDUN LO FẸẸ DA NNKAN RU FUN YAYI L'OGUN NI ABI AWỌN AṢOFIN YII
15K views · Nov 23, 2026 · News & Politics
Comments · 20
@mariamasiemasie8874 · 1 day ago
Nigeria politicians are not for people of Nigeria but for themselves
1
@kehindejosephkashimawo9410 · 2 days ago (edited)
Problem wà fun Yayi àti APC ni Ogun State pelu oun ti mọ gbọ́ yìí. Toripe to bá jẹ wípé Lòótọ́ wọn kò ṣe idibo primary, tí àwọn kan kàn lọ fà Yayi lọwọ́ sókè.. Tó ba wọlé idibo gan wọn le já bọ́. Kí ilé Ẹjọ́ yàn ẹni tó kàn, tó díje ninu ẹgbẹ́ òṣèlú tó bá tẹ̀ lé. Ìyẹn tí alátakọ̀ bá ní wọn kò ṣe idibo abẹ́lé.. . Èyí a sì burú púpọ̀ fún APC ni Ogun. Òní katikàti làwọn oloselu yìí. Àwọn míì lè lọ darapo mọ́ egbe oselu míì.. Ko si eyi tó nìfẹ́ ara ilu tààrà nínú wọn. Ìkan na ni wọ́n. Mo ṣàkíyèsí pé Aṣòfin Opeyemi Bamidele fi ọwọ́ mejeji tí Yayi sapá ẹ̀yìn ìtàgé kò tó sọ̀rọ̀ níbi ìpolongo idibo tí wọ́n ṣe ni Ibadan yẹn. Nigbati Bamidele fẹ́ sọ̀rọ̀.. Ko to di asiko ti Tinubu faa lọwọ sókè yẹn.. Ẹ lọ wòó... Wọ́n ni lati yanjú ọ̀rọ̀ yẹn kí àwọn tó kù bù omi suuru mu. Bí bẹ́ẹ̀kọ́?! Hùùùn!!!
3
@RamatBukola-iw2oh · 1 day ago
OLOHUN aba yin yanjue
@olusolaayindefakeye4426 · 22 hours ago
Omo Yewa ni Yayi a si mo eyi daradara. Yayi la fe gegebi Gomina Eyin olote, e yè se ote
@TajudeenAdetunji-vz5cn · 1 day ago
Eku ise opolo, ejowo esoro lori oselu Kwara na
1
@isaacadebayo7802 · 1 day ago
Òṣèlú nigeria hmmmm 😮
2
@olusolaayindefakeye4426 · 22 hours ago
Yayi ni awa omo Yewa fe gegebi Gomina ti a fe dibo fun.
@AdedejiPeter-h9h · 1 day ago
I give you new title, Chief ojutole ojutoko,
1
@MOOYE66 · 1 day ago
E sare tele Yoruba e gbagbe yayi
1
@kamalmustapha9317 · 1 day ago
People choice is the ultimate 👌 🙌
@imamabdulrasaq401 · 1 day ago
Hmmmm<br>Awọn oloselu pẹlu ọwọ agbara buruku lori ara wọn
@dejidan8312 · 1 day ago
Bi iku ile ko pa ni, ti ode o le pa ni. Gbogbo aiye lo ri gedegbe ni igba ti won fa Yaayi kale. Koda Iyabo Obasanjo wa ni kale.E ranti wipe, opo la pe, die la yan. Eni ti Olorun ba yan Yaayi, opo esinsin ko le yoo.
Up next

Why did China send a Pakistani astronaut into space? | BBC News
BBC News · 266K views

WỌN TI DA A DURO O, ẸẸMAYA TO FẸE FỌMU OYINBO ṢERE LAAFIN Ẹ
Alaroye onlinetv · 2.3K views

Pakistani becomes first foreigner to join China's space station | AFP
AFP News Agency · 3K views

Sadiq Khan breaks silence over Met Police's 'systemic racism and misogyny'
The London Standard · 2.1K views

EYI NI BI IJA TINUBU PẸLU AWỌN ỌMỌ IBO EKO ṢE PARI
YORUBA WORLD CENTRE · 12K views

NO DEAL AS ACRIMONOUS COP31 SUMMIT ENDS IN TURKIYE
Arise News · 3.2K views

Simon Jordan reacts to Raheem Sterling being given a suspended jail sentence for dangerous driving
talkSPORT · 4.8K views

Ẹ GBA ISLAM TÀBÍ KẸ KÚ! ÀWỌN FÚLÀNÍ GA ÀWỌN CHRISTIAN LỌ́RÙN MỌLẸ WỌ́N FÚN WỌN LÓMI BÁTÌRÌ MU LÁGÍDÍ
A.L.F YORUBA TV · 37 views

EU Students Should Pay The Same Tuition Fees As Domestic Students In The UK | Michel Barnier
Times Radio · 5.1K views

Can the government fix the ‘dehumanising’ disability benefits system? | BBC Newscast
BBC News · 28K views

“SEYI’S DISRESPECT TO TINUBU IS COMPLETELY UNCALLED FOR!” — OBINNA
TV Afrikana · 18K views

Who is to blame for the 'staggering' energy costs?
LBC and LBC UK Politics · 1.2K views

Advice for homeowners with energy bills to rise by 26% from January | BBC Breakfast
BBC Politics · 13K views

Moment China launches Shenzhou-24 mission with Pakistani astronaut aboard
Euronews Next · 3.2K views

ORO BEYIN YO O!! ASIRI ORIYOMI ATI SAKIRULAHI ORANKAN LORI ORO 10,000 MOSQUE, 200 HOSPITAL & ILE IWE
YORUBA SPACE TV · 3.6K views

Video shows massive explosion as US Army destroys entire stockpile of lead azide
euronews · 1.6K views

Pete Edochie - Age, Career, Wives, Children, Net worth, Mansions & Cars
Ejimozy · 25K views

My Honest Take on DJ Kulet’s Outbursts Against Pasuma and His Band Boys
Adiitu Edumare Tv · 17K views

LẸẸKAN SI I, ATIKU TUN RANṢẸ IKILỌ SI PETER OBI ATI ṢEYI MAKINDE
YORUBA WORLD CENTRE · 14K views

Hear what Saheed Osupa Says About Seyi Makinde That Shøck Everyone At City Boy Rally In Ibadan
PLUS MEDIA TV · 68K views